-
Nehemáyà 12:38, 39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Ẹgbẹ́ akọrin ọpẹ́ kejì gba òdìkejì* lọ, èmi àti ìdajì àwọn èèyàn náà sì tẹ̀ lé wọn, lórí ògiri lókè Ilé Gogoro Ààrò+ títí dé orí Ògiri Fífẹ̀+ 39 àti lókè Ẹnubodè Éfúrémù+ títí dé Ẹnubodè Ìlú Àtijọ́+ àti títí dé Ẹnubodè Ẹja,+ Ilé Gogoro Hánánélì,+ Ilé Gogoro Méà àti títí dé Ẹnubodè Àgùntàn;+ wọ́n sì dúró ní Ẹnubodè Ẹ̀ṣọ́.
-