Léfítíkù 2:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “‘Tí o bá fẹ́ ṣe ọrẹ ọkà àkọ́pọ́n èso rẹ fún Jèhófà, ọkà tuntun* tí o yan lórí iná ni kí o mú wá, kóró tuntun tí o kò lọ̀ kúnná, kí o fi ṣe ọrẹ ọkà àkọ́pọ́n èso+ rẹ. 15 Kí o da òróró sórí rẹ̀, kí o sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀. Ọrẹ ọkà ni.
14 “‘Tí o bá fẹ́ ṣe ọrẹ ọkà àkọ́pọ́n èso rẹ fún Jèhófà, ọkà tuntun* tí o yan lórí iná ni kí o mú wá, kóró tuntun tí o kò lọ̀ kúnná, kí o fi ṣe ọrẹ ọkà àkọ́pọ́n èso+ rẹ. 15 Kí o da òróró sórí rẹ̀, kí o sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀. Ọrẹ ọkà ni.