Nehemáyà 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wọ́n kọ ọ́ sínú rẹ̀ pé: “A ti gbọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, Géṣémù+ sì ń sọ ọ́ pé, ìwọ àti àwọn Júù ń gbèrò láti dìtẹ̀.+ Ìdí nìyẹn tí o fi ń mọ ògiri náà; ohun tí wọ́n ń sọ sì fi hàn pé ìwọ lo máa di ọba wọn.
6 Wọ́n kọ ọ́ sínú rẹ̀ pé: “A ti gbọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, Géṣémù+ sì ń sọ ọ́ pé, ìwọ àti àwọn Júù ń gbèrò láti dìtẹ̀.+ Ìdí nìyẹn tí o fi ń mọ ògiri náà; ohun tí wọ́n ń sọ sì fi hàn pé ìwọ lo máa di ọba wọn.