-
Diutarónómì 25:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Tí ẹgba bá tọ́ sí ẹni burúkú náà,+ kí adájọ́ dá a dọ̀bálẹ̀, kí wọ́n sì nà án níṣojú rẹ̀. Bí ohun tó ṣe bá ṣe burú tó ni kí iye ẹgba tó máa jẹ ṣe pọ̀ tó.
-
-
Ẹ́sírà 7:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Gbogbo ẹni tí kò bá pa Òfin Ọlọ́run rẹ àti òfin ọba mọ́ ni kí wọ́n dá lẹ́jọ́ ní kánmọ́kánmọ́, ì báà jẹ́ ìdájọ́ ikú tàbí lílé kúrò láwùjọ tàbí owó ìtanràn tàbí ìfisẹ́wọ̀n.”
-