Ẹ́sítà 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nínú àkọsílẹ̀ náà, wọ́n rí ohun tí Módékáì sọ nípa Bígítánà àti Téréṣì, àwọn òṣìṣẹ́ méjì láàfin ọba tí wọ́n jẹ́ aṣọ́nà, àwọn tó gbìmọ̀ pọ̀ láti pa* Ọba Ahasuérúsì.+
2 Nínú àkọsílẹ̀ náà, wọ́n rí ohun tí Módékáì sọ nípa Bígítánà àti Téréṣì, àwọn òṣìṣẹ́ méjì láàfin ọba tí wọ́n jẹ́ aṣọ́nà, àwọn tó gbìmọ̀ pọ̀ láti pa* Ọba Ahasuérúsì.+