-
Ẹ́sítà 2:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Torí náà, wọ́n wádìí ọ̀rọ̀ náà, wọ́n sì rí i nígbà tó yá pé òótọ́ ni, wọ́n wá gbé àwọn méjèèjì kọ́ sórí òpó igi; wọ́n kọ gbogbo rẹ̀ sílẹ̀ níṣojú ọba, sínú ìwé ìtàn àkókò náà.+
-