Ẹ́sítà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Gbogbo àwọn olórí tó wà ní àwọn ìpínlẹ̀,* àwọn baálẹ̀,+ àwọn gómìnà àti àwọn tó ń bójú tó iṣẹ́ ọba ń ti àwọn Júù lẹ́yìn, torí ẹ̀rù Módékáì ń bà wọ́n.
3 Gbogbo àwọn olórí tó wà ní àwọn ìpínlẹ̀,* àwọn baálẹ̀,+ àwọn gómìnà àti àwọn tó ń bójú tó iṣẹ́ ọba ń ti àwọn Júù lẹ́yìn, torí ẹ̀rù Módékáì ń bà wọ́n.