Dáníẹ́lì 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó dáa lójú Dáríúsì kó fi ọgọ́fà (120) baálẹ̀ jẹ lórí gbogbo ìjọba náà.+