Ẹ́sítà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Nígbà ayé Ahasuérúsì,* ìyẹn Ahasuérúsì tó ṣàkóso ìpínlẹ̀* mẹ́tàdínláàádóje+ (127) láti Íńdíà títí dé Etiópíà,* Dáníẹ́lì 9:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ní ọdún kìíní Dáríúsì+ ọmọ Ahasuérúsì, àtọmọdọ́mọ àwọn ará Mídíà, ẹni tí wọ́n fi jọba lórí ìjọba àwọn ará Kálídíà,+
1 Nígbà ayé Ahasuérúsì,* ìyẹn Ahasuérúsì tó ṣàkóso ìpínlẹ̀* mẹ́tàdínláàádóje+ (127) láti Íńdíà títí dé Etiópíà,*
9 Ní ọdún kìíní Dáríúsì+ ọmọ Ahasuérúsì, àtọmọdọ́mọ àwọn ará Mídíà, ẹni tí wọ́n fi jọba lórí ìjọba àwọn ará Kálídíà,+