-
Sáàmù 124:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Ká ní Jèhófà ò wà pẹ̀lú wa ni+
Nígbà tí àwọn èèyàn dìde láti bá wa jà,+
-
Sáàmù 124:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ìyìn ni fún Jèhófà,
Torí kò fi wá ṣe ẹran ìjẹ fún eyín wọn.
-
-
-