Ẹ́sítà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Nígbà ayé Ahasuérúsì,* ìyẹn Ahasuérúsì tó ṣàkóso ìpínlẹ̀* mẹ́tàdínláàádóje+ (127) láti Íńdíà títí dé Etiópíà,*
1 Nígbà ayé Ahasuérúsì,* ìyẹn Ahasuérúsì tó ṣàkóso ìpínlẹ̀* mẹ́tàdínláàádóje+ (127) láti Íńdíà títí dé Etiópíà,*