Ẹ́sírà 4:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 kí o lè wádìí nínú àkọsílẹ̀ àwọn baba ńlá rẹ.+ Wàá rí i nínú àkọsílẹ̀ pé ìlú yẹn jẹ́ ìlú ọ̀tẹ̀, ó máa ń pa àwọn ọba àti àwọn ìpínlẹ̀* lára, ó sì ti pẹ́ tí àwọn tó wà nínú rẹ̀ ti máa ń dìtẹ̀. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi pa ìlú náà run.+ Ẹ́sítà 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní òru ọjọ́ yẹn, ọba ò rí oorun sùn.* Torí náà, ó ní kí wọ́n mú ìwé àkọsílẹ̀ ìtàn àwọn àkókò+ wá, wọ́n sì kà á fún ọba.
15 kí o lè wádìí nínú àkọsílẹ̀ àwọn baba ńlá rẹ.+ Wàá rí i nínú àkọsílẹ̀ pé ìlú yẹn jẹ́ ìlú ọ̀tẹ̀, ó máa ń pa àwọn ọba àti àwọn ìpínlẹ̀* lára, ó sì ti pẹ́ tí àwọn tó wà nínú rẹ̀ ti máa ń dìtẹ̀. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi pa ìlú náà run.+
6 Ní òru ọjọ́ yẹn, ọba ò rí oorun sùn.* Torí náà, ó ní kí wọ́n mú ìwé àkọsílẹ̀ ìtàn àwọn àkókò+ wá, wọ́n sì kà á fún ọba.