Ẹ́sítà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní ti gbogbo ohun tó fi agbára àti okun rẹ̀ gbé ṣe, títí kan kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa ipò gíga tí ọba gbé Módékáì+ sí,+ ǹjẹ́ wọn kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn àkókò+ àwọn ọba Mídíà àti Páṣíà?+
2 Ní ti gbogbo ohun tó fi agbára àti okun rẹ̀ gbé ṣe, títí kan kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa ipò gíga tí ọba gbé Módékáì+ sí,+ ǹjẹ́ wọn kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn àkókò+ àwọn ọba Mídíà àti Páṣíà?+