Dáníẹ́lì 6:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n sọ fún ọba lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pé: “Dáníẹ́lì, ọ̀kan lára àwọn ìgbèkùn Júdà,+ kò ka ìwọ ọba sí, kò sì ka òfin tí o fọwọ́ sí sí, àmọ́ ẹ̀ẹ̀mẹta lójúmọ́ ló ń gbàdúrà.”+
13 Wọ́n sọ fún ọba lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pé: “Dáníẹ́lì, ọ̀kan lára àwọn ìgbèkùn Júdà,+ kò ka ìwọ ọba sí, kò sì ka òfin tí o fọwọ́ sí sí, àmọ́ ẹ̀ẹ̀mẹta lójúmọ́ ló ń gbàdúrà.”+