-
Dáníẹ́lì 2:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Áríókù yára mú Dáníẹ́lì wọlé síwájú ọba, ó sì sọ fún un pé: “Mo ti rí ọkùnrin kan lára àwọn tí wọ́n kó nígbèkùn ní Júdà,+ tó lè sọ ìtumọ̀ náà fún ọba.”
-