Ẹ́sítà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lọ́jọ́ náà, tayọ̀tayọ̀ ni Hámánì fi jáde lọ, inú rẹ̀ sì ń dùn. Ṣùgbọ́n nígbà tí Hámánì rí Módékáì ní ẹnubodè ọba, tó sì rí i pé kò dìde, kò sì wárìrì níwájú òun, inú bí Hámánì gan-an sí Módékáì.+
9 Lọ́jọ́ náà, tayọ̀tayọ̀ ni Hámánì fi jáde lọ, inú rẹ̀ sì ń dùn. Ṣùgbọ́n nígbà tí Hámánì rí Módékáì ní ẹnubodè ọba, tó sì rí i pé kò dìde, kò sì wárìrì níwájú òun, inú bí Hámánì gan-an sí Módékáì.+