Ẹ́sítà 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Hábónà,+ ọ̀kan lára àwọn òṣìṣẹ́ ààfin ọba wá sọ pé: “Hámánì tún ṣe òpó igi kan fún Módékáì,+ ẹni tó sọ ohun tó gba ọba sílẹ̀.+ Òpó náà wà ní òró ní ilé Hámánì, àádọ́ta (50) ìgbọ̀nwọ́* ni gíga rẹ̀.” Ni ọba bá sọ pé: “Ẹ gbé e kọ́ sórí rẹ̀.”
9 Hábónà,+ ọ̀kan lára àwọn òṣìṣẹ́ ààfin ọba wá sọ pé: “Hámánì tún ṣe òpó igi kan fún Módékáì,+ ẹni tó sọ ohun tó gba ọba sílẹ̀.+ Òpó náà wà ní òró ní ilé Hámánì, àádọ́ta (50) ìgbọ̀nwọ́* ni gíga rẹ̀.” Ni ọba bá sọ pé: “Ẹ gbé e kọ́ sórí rẹ̀.”