Nọ́ńbà 24:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Omi ń sun látinú àwọn korobá rẹ̀ méjì tí wọ́n fi awọ ṣe,Etí omi+ ló sì gbin àwọn irúgbìn* rẹ̀ sí. Ọba+ rẹ̀ pẹ̀lú yóò ju Ágágì+ lọ,Wọ́n á sì gbé ìjọba rẹ̀ ga.+ 1 Sámúẹ́lì 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó mú Ágágì+ ọba Ámálékì láàyè, àmọ́ ó fi idà pa gbogbo àwọn èèyàn tó ṣẹ́ kù run.+ 1 Sámúẹ́lì 15:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Sámúẹ́lì wá sọ pé: “Ẹ mú Ágágì ọba Ámálékì sún mọ́ mi.” Ni ara bá ń ti Ágágì láti* lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ nítorí Ágágì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: ‘Ó dájú pé ikú* ti yẹ̀ lórí mi.’
7 Omi ń sun látinú àwọn korobá rẹ̀ méjì tí wọ́n fi awọ ṣe,Etí omi+ ló sì gbin àwọn irúgbìn* rẹ̀ sí. Ọba+ rẹ̀ pẹ̀lú yóò ju Ágágì+ lọ,Wọ́n á sì gbé ìjọba rẹ̀ ga.+
32 Sámúẹ́lì wá sọ pé: “Ẹ mú Ágágì ọba Ámálékì sún mọ́ mi.” Ni ara bá ń ti Ágágì láti* lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ nítorí Ágágì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: ‘Ó dájú pé ikú* ti yẹ̀ lórí mi.’