-
Ẹ́sítà 8:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ní báyìí, ẹ kọ ohunkóhun tó bá dáa lójú yín lórúkọ ọba nítorí àwọn Júù, kí ẹ sì fi òrùka àṣẹ ọba gbé èdìdì lé e, nítorí ìwé àṣẹ tí wọ́n bá kọ lórúkọ ọba, tí wọ́n sì fi òrùka àṣẹ ọba gbé èdìdì lé kò ṣeé yí pa dà.”+
-
-
Dáníẹ́lì 6:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Wọ́n wá gbé òkúta kan wá, wọ́n sì fi dí ẹnu ihò náà, ọba sì fi òrùka àṣẹ rẹ̀ àti òrùka àṣẹ àwọn èèyàn rẹ̀ pàtàkì gbé èdìdì lé e, kí wọ́n má bàa yí ohunkóhun pa dà lórí ọ̀rọ̀ Dáníẹ́lì.
-