Dáníẹ́lì 6:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní báyìí, ọba, gbé àṣẹ náà kalẹ̀, kí o sì fọwọ́ sí i,+ kó má ṣeé yí pa dà, gẹ́gẹ́ bí òfin àwọn ará Mídíà àti Páṣíà, tí kò ṣeé fagi lé.”+ Dáníẹ́lì 6:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Níkẹyìn, àwọn ọkùnrin yẹn jọ lọ sọ́dọ̀ ọba, wọ́n sì sọ fún ọba pé: “Ọba, rántí pé òfin àwọn ará Mídíà àti Páṣíà ni pé ìfòfindè tàbí àṣẹ èyíkéyìí tí ọba bá gbé kalẹ̀ kò ṣeé yí pa dà.”+
8 Ní báyìí, ọba, gbé àṣẹ náà kalẹ̀, kí o sì fọwọ́ sí i,+ kó má ṣeé yí pa dà, gẹ́gẹ́ bí òfin àwọn ará Mídíà àti Páṣíà, tí kò ṣeé fagi lé.”+
15 Níkẹyìn, àwọn ọkùnrin yẹn jọ lọ sọ́dọ̀ ọba, wọ́n sì sọ fún ọba pé: “Ọba, rántí pé òfin àwọn ará Mídíà àti Páṣíà ni pé ìfòfindè tàbí àṣẹ èyíkéyìí tí ọba bá gbé kalẹ̀ kò ṣeé yí pa dà.”+