Ẹ́sítà 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní ọjọ́ kẹta,+ Ẹ́sítà wọ aṣọ ayaba, ó sì dúró ní àgbàlá inú ilé* ọba ní òdìkejì ààfin ọba, ọba jókòó lórí ìtẹ́ nínú ilé ọba tó wà ní òdìkejì ẹnu ọ̀nà.
5 Ní ọjọ́ kẹta,+ Ẹ́sítà wọ aṣọ ayaba, ó sì dúró ní àgbàlá inú ilé* ọba ní òdìkejì ààfin ọba, ọba jókòó lórí ìtẹ́ nínú ilé ọba tó wà ní òdìkejì ẹnu ọ̀nà.