Ẹ́sítà 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọba tún béèrè lọ́wọ́ Ẹ́sítà ní ọjọ́ kejì nígbà tí wọ́n ń mu wáìnì lọ́wọ́ pé: “Ẹ́sítà Ayaba, kí lo fẹ́ tọrọ? A ó fi fún ọ. Kí lo sì fẹ́ béèrè? Kódà tí ó bá tó* ìdajì ìjọba mi, a ó ṣe é fún ọ!”+
2 Ọba tún béèrè lọ́wọ́ Ẹ́sítà ní ọjọ́ kejì nígbà tí wọ́n ń mu wáìnì lọ́wọ́ pé: “Ẹ́sítà Ayaba, kí lo fẹ́ tọrọ? A ó fi fún ọ. Kí lo sì fẹ́ béèrè? Kódà tí ó bá tó* ìdajì ìjọba mi, a ó ṣe é fún ọ!”+