Ẹ́sítà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọba béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Ẹ́sítà Ayaba, ṣé kò sí o? Kí lo fẹ́ béèrè? Kódà tí ó bá tó* ìdajì ìjọba mi, a ó fi fún ọ!” Ẹ́sítà 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Lẹ́yìn àkókò díẹ̀, nígbà tí wọ́n ń mu wáìnì lọ́wọ́, ọba sọ fún Ẹ́sítà pé: “Kí lo fẹ́ tọrọ? A ó fi fún ọ! Kí lo sì fẹ́ béèrè? Kódà tí ó bá tó* ìdajì ìjọba mi, a ó ṣe é fún ọ!”+
3 Ọba béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Ẹ́sítà Ayaba, ṣé kò sí o? Kí lo fẹ́ béèrè? Kódà tí ó bá tó* ìdajì ìjọba mi, a ó fi fún ọ!”
6 Lẹ́yìn àkókò díẹ̀, nígbà tí wọ́n ń mu wáìnì lọ́wọ́, ọba sọ fún Ẹ́sítà pé: “Kí lo fẹ́ tọrọ? A ó fi fún ọ! Kí lo sì fẹ́ béèrè? Kódà tí ó bá tó* ìdajì ìjọba mi, a ó ṣe é fún ọ!”+