Ẹ́sítà 9:7-10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n tún pa Páṣáńdátà, Dálífónì, Ásípátà, 8 Pọ́rátà, Adalíà, Árídátà, 9 Pámáṣítà, Árísáì, Árídáì àti Fáísátà, 10 àwọn ọmọkùnrin mẹ́wẹ̀ẹ̀wá Hámánì ọmọ Hamédátà, ọ̀tá àwọn Júù.+ Àmọ́ lẹ́yìn tí wọ́n pa wọ́n, wọn ò kó ohun ìní èyíkéyìí.+
7 Wọ́n tún pa Páṣáńdátà, Dálífónì, Ásípátà, 8 Pọ́rátà, Adalíà, Árídátà, 9 Pámáṣítà, Árísáì, Árídáì àti Fáísátà, 10 àwọn ọmọkùnrin mẹ́wẹ̀ẹ̀wá Hámánì ọmọ Hamédátà, ọ̀tá àwọn Júù.+ Àmọ́ lẹ́yìn tí wọ́n pa wọ́n, wọn ò kó ohun ìní èyíkéyìí.+