- 
	                        
            
            Jóòbù 5:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        8 Àmọ́ màá mú ọ̀rọ̀ mi tọ Ọlọ́run lọ, Ọlọ́run sì ni màá gbé ẹjọ́ mi lọ bá, 9 Sọ́dọ̀ Ẹni tó ń ṣe àwọn ohun ńlá àtàwọn ohun àwámáridìí, Àwọn ohun àgbàyanu tí kò níye. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jóòbù 11:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Ká ní o lè múra ọkàn rẹ sílẹ̀ ni, Kí o sì na ọwọ́ rẹ sí i. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jóòbù 22:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 Tí o bá pa dà sọ́dọ̀ Olódùmarè, wàá pa dà sí àyè rẹ;+ Tí o bá mú àìṣòdodo kúrò ní àgọ́ rẹ, 
 
-