Jóòbù 8:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àmọ́ tí o bá lè yíjú sí Ọlọ́run,+Kí o sì bẹ Olódùmarè pé kó ṣojúure sí ọ, 6 Tó bá jẹ́ pé òótọ́ lo mọ́, tí o sì jẹ́ olódodo,+Ó máa fetí sí ọ,*Ó sì máa dá ọ pa dà sí ibi tó tọ́ sí ọ.
5 Àmọ́ tí o bá lè yíjú sí Ọlọ́run,+Kí o sì bẹ Olódùmarè pé kó ṣojúure sí ọ, 6 Tó bá jẹ́ pé òótọ́ lo mọ́, tí o sì jẹ́ olódodo,+Ó máa fetí sí ọ,*Ó sì máa dá ọ pa dà sí ibi tó tọ́ sí ọ.