Diutarónómì 32:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.
22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.