Jóòbù 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ọjọ́ mi ń yára sáré ju ohun èlò tí wọ́n fi ń hun aṣọ,+Wọ́n sì dópin láìnírètí.+ Sáàmù 90:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àádọ́rin (70) ọdún ni gígùn ọjọ́ ayé wa,Tàbí kó jẹ́ ọgọ́rin (80) ọdún+ tí èèyàn bá lókun tó ṣàrà ọ̀tọ̀.* Síbẹ̀, wàhálà àti ìbànújẹ́ ló kún inú wọn;Wọ́n á kọjá lọ kíákíá, a ó sì fò lọ.+ Jémíìsì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 bẹ́ẹ̀ sì rèé, ẹ ò mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí yín lọ́la.+ Torí ìkùukùu ni yín, tó máa ń wà fúngbà díẹ̀, lẹ́yìn náà tí á pòórá.+
10 Àádọ́rin (70) ọdún ni gígùn ọjọ́ ayé wa,Tàbí kó jẹ́ ọgọ́rin (80) ọdún+ tí èèyàn bá lókun tó ṣàrà ọ̀tọ̀.* Síbẹ̀, wàhálà àti ìbànújẹ́ ló kún inú wọn;Wọ́n á kọjá lọ kíákíá, a ó sì fò lọ.+
14 bẹ́ẹ̀ sì rèé, ẹ ò mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí yín lọ́la.+ Torí ìkùukùu ni yín, tó máa ń wà fúngbà díẹ̀, lẹ́yìn náà tí á pòórá.+