ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 119:73
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 73 Ọwọ́ rẹ ni ó dá mi, tí ó sì mọ mí.

      Fún mi ní òye,+

      Kí n lè kọ́ àwọn àṣẹ rẹ.

  • Sáàmù 139:13-16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ìwọ lo ṣe àwọn kíndìnrín mi;

      O yà mí sọ́tọ̀* ní inú ìyá mi.+

      14 Mo yìn ọ́ nítorí pé lọ́nà tó ń bani lẹ́rù ni o ṣẹ̀dá mi tìyanutìyanu.+

      Àgbàyanu ni àwọn iṣẹ́ rẹ,+

      Mo* mọ èyí dáadáa.

      15 Àwọn egungun mi ò pa mọ́ fún ọ

      Nígbà tí o ṣẹ̀dá mi ní ìkọ̀kọ̀,

      Nígbà tí o hun mí ní ìsàlẹ̀ ayé.+

      16 Kódà, ojú rẹ rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn;*

      Gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé rẹ

      Ní ti àwọn ọjọ́ tí o ṣẹ̀dá wọn,

      Kí ìkankan lára wọn tó wà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́