- 
	                        
            
            Sáàmù 22:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Ìwọ ni Ó gbé mi jáde láti inú ìyá mi,+ Ìwọ ni O mú kí ọkàn mi balẹ̀ ní àyà ìyá mi. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 71:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Ìwọ ni mo gbára lé láti ìgbà tí wọ́n ti bí mi; Ìwọ ló gbé mi jáde látinú ìyá mi.+ Gbogbo ìgbà ni mò ń yìn ọ́. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 1:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Mo fi ọ́ ṣe wòlíì àwọn orílẹ̀-èdè.” 
 
-