-
Jóòbù 23:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ká ní mo mọ ibi tí mo ti lè rí Ọlọ́run ni!+
Ǹ bá lọ sí ibùgbé rẹ̀.+
4 Màá ro ẹjọ́ mi níwájú rẹ̀,
Màá sì fi gbogbo ẹnu mi gbèjà ara mi;
-