Jóòbù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wò ó! Mò ń ké ṣáá pé, ‘Ìwà ipá!’ àmọ́ kò sẹ́ni tó dáhùn;+Mò ń kígbe ṣáá pé mo nílò ìrànlọ́wọ́, àmọ́ kò sí ìdájọ́ òdodo.+
7 Wò ó! Mò ń ké ṣáá pé, ‘Ìwà ipá!’ àmọ́ kò sẹ́ni tó dáhùn;+Mò ń kígbe ṣáá pé mo nílò ìrànlọ́wọ́, àmọ́ kò sí ìdájọ́ òdodo.+