Jóòbù 19:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí ó dá mi lójú pé olùràpadà*+ mi wà láàyè;Ó máa wá tó bá yá, ó sì máa dìde lórí ayé.*