- 
	                        
            
            Sáàmù 69:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        18 Sún mọ́ mi, kí o sì gbà mí sílẹ̀;* Gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 103:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Ó gba ẹ̀mí mi pa dà látinú kòtò,*+ Ó sì fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti àánú dé mi ládé,+ 
 
-