Jóòbù 31:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ká ní ẹnì kan lè fetí sí mi ni!+ Ǹ bá buwọ́ lùwé sí ohun tí mo sọ.* Kí Olódùmarè dá mi lóhùn!+ Ká ní ẹni tó fẹ̀sùn kàn mí ti kọ ẹ̀sùn náà sínú ìwé ni!
35 Ká ní ẹnì kan lè fetí sí mi ni!+ Ǹ bá buwọ́ lùwé sí ohun tí mo sọ.* Kí Olódùmarè dá mi lóhùn!+ Ká ní ẹni tó fẹ̀sùn kàn mí ti kọ ẹ̀sùn náà sínú ìwé ni!