Sáàmù 55:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ jọ̀lọ̀ ju bọ́tà lọ,+Àmọ́ ìjà ló wà lọ́kàn rẹ̀. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ tuni lára ju òróró lọ,Àmọ́ idà tí a fà yọ ni wọ́n.+ Òwe 12:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọ̀rọ̀ téèyàn sọ láìronú dà bí ìgbà tí idà gúnni,Àmọ́ ahọ́n ọlọ́gbọ́n ń woni sàn.+
21 Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ jọ̀lọ̀ ju bọ́tà lọ,+Àmọ́ ìjà ló wà lọ́kàn rẹ̀. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ tuni lára ju òróró lọ,Àmọ́ idà tí a fà yọ ni wọ́n.+