Jóòbù 31:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Kò sí àlejò* tó sun ìta mọ́jú;+Mo ṣí ilẹ̀kùn mi sílẹ̀ fún arìnrìn-àjò.