ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 5:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Wọ́n ní háàpù àti ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín,

      Ìlù tanboríìnì, fèrè àti wáìnì sì wà níbi àsè wọn;

      Àmọ́ wọn ò ronú nípa iṣẹ́ Jèhófà,

      Wọn ò sì rí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

  • Àìsáyà 22:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Àmọ́ dípò ìyẹn, wọ́n ń yọ̀, inú wọn sì ń dùn,

      Wọ́n ń pa màlúù, wọ́n sì ń dúńbú àgùntàn,

      Wọ́n ń jẹ ẹran, wọ́n sì ń mu wáìnì.+

      ‘Ẹ jẹ́ ká máa jẹ, ká sì máa mu, torí ọ̀la la máa kú.’”+

  • Émọ́sì 6:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Wọ́n ń dùbúlẹ̀ sórí àwọn ibùsùn tí wọ́n fi eyín erin ṣe,+ wọ́n sì ń nà gbalaja sórí àga tìmùtìmù,+

      Wọ́n ń jẹ àwọn àgbò inú agbo ẹran àti àwọn ọmọ màlúù* tí wọ́n bọ́ sanra;+

       5 Wọ́n ń kọ orin sí ìró háàpù,*+

      Bíi Dáfídì, wọ́n ṣe àwọn ohun èlò ìkọrin;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́