Sáàmù 22:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nítorí kò gbójú fo ìyà tó ń jẹ ẹni tí ara ń ni, kò sì ṣàìka ìpọ́njú rẹ̀ sí;+Kò gbé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún un.+ Nígbà tó ké pè é fún ìrànlọ́wọ́, ó gbọ́.+ Àìsáyà 57:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí mi ò ní ta kò wọ́n títí láé,Mi ò sì ní máa bínú títí lọ;+Torí àárẹ̀ máa bá ẹ̀mí èèyàn nítorí mi,+Títí kan àwọn ohun tó ń mí, tí mo dá.
24 Nítorí kò gbójú fo ìyà tó ń jẹ ẹni tí ara ń ni, kò sì ṣàìka ìpọ́njú rẹ̀ sí;+Kò gbé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún un.+ Nígbà tó ké pè é fún ìrànlọ́wọ́, ó gbọ́.+
16 Torí mi ò ní ta kò wọ́n títí láé,Mi ò sì ní máa bínú títí lọ;+Torí àárẹ̀ máa bá ẹ̀mí èèyàn nítorí mi,+Títí kan àwọn ohun tó ń mí, tí mo dá.