-
Diutarónómì 19:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Tí o bá gba ogún rẹ ní ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run fẹ́ fún ọ pé kó di tìrẹ, o ò gbọ́dọ̀ sún ààlà ọmọnìkejì rẹ sẹ́yìn + kúrò níbi tí àwọn baba ńlá fi sí.
-
-
Òwe 23:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Má ṣe sún ààlà àtọjọ́mọ́jọ́ sẹ́yìn,+
Má sì wọnú ilẹ̀ àwọn aláìníbaba.
-