ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 12:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Kí ló dé tí o kò fi ka ọ̀rọ̀ Jèhófà sí, tí o wá ṣe ohun tó burú lójú rẹ̀? O fi idà pa+ Ùráyà ọmọ Hétì! Lẹ́yìn náà, o sọ ìyàwó rẹ̀ di tìrẹ+ lẹ́yìn tí o ti mú kí idà àwọn ọmọ Ámónì pa á.+

  • 2 Sámúẹ́lì 12:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìkọ̀kọ̀+ ni o ti ṣe é, iwájú gbogbo Ísírẹ́lì ni màá ti ṣe ohun tí mo sọ yìí ní ọ̀sán gangan.’”*

  • Sáàmù 94:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ìgbà wo, Jèhófà,

      Ìgbà wo ni àwọn ẹni burúkú ò ní yọ̀ mọ́?+

  • Sáàmù 94:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Wọ́n ń sọ pé: “Jáà kò rí i;+

      Ọlọ́run Jékọ́bù kò kíyè sí i.”+

  • Òwe 30:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ọ̀nà obìnrin alágbèrè nìyí:

      Ó jẹun, ó nu ẹnu rẹ̀;

      Ó sì sọ pé, “Mi ò ṣe nǹkan kan tó burú.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́