-
Oníwàásù 11:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Tí òjò bá ṣú lójú ọ̀run, á rọ̀ sórí ilẹ̀; tí igi kan bá sì ṣubú sí gúúsù tàbí sí àríwá, ibi tí igi náà ṣubú sí, ibẹ̀ ló máa wà.
-