Àìsáyà 40:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ta ló ti fi àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ wọn omi,+Tó sì ti fi ìbú àtẹ́lẹwọ́* rẹ̀ wọn* ọ̀run? Ta ló ti kó gbogbo erùpẹ̀ ilẹ̀ sínú òṣùwọ̀n,+Tàbí tó ti wọn àwọn òkè ńlá lórí ìwọ̀n,Tó sì ti wọn àwọn òkè kéékèèké lórí òṣùwọ̀n?
12 Ta ló ti fi àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ wọn omi,+Tó sì ti fi ìbú àtẹ́lẹwọ́* rẹ̀ wọn* ọ̀run? Ta ló ti kó gbogbo erùpẹ̀ ilẹ̀ sínú òṣùwọ̀n,+Tàbí tó ti wọn àwọn òkè ńlá lórí ìwọ̀n,Tó sì ti wọn àwọn òkè kéékèèké lórí òṣùwọ̀n?