-
Jóòbù 22:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Élífásì+ ará Témánì fèsì pé:
-
-
Jóòbù 22:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ṣé kì í ṣe torí pé ìwà burúkú rẹ pọ̀ jù ni,
Tí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ ò sì lópin?+
-