Sáàmù 73:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí mo jowú àwọn agbéraga*Nígbà tí mo rí àlàáfíà àwọn ẹni burúkú.+ Sáàmù 73:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ wo bí wọ́n ti pa rẹ́ lójijì!+ Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá wọn lójijì, tí wọ́n sì pa run!