Òwe 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+ Málákì 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó máa jókòó bí ẹni tó ń yọ́ fàdákà, tó sì ń fọ̀ ọ́ mọ́,+ ó sì máa fọ àwọn ọmọ Léfì mọ́; á sì yọ́ wọn mọ́* bíi wúrà àti fàdákà, ó sì dájú pé wọ́n á fi ọkàn òdodo mú ọrẹ wá fún Jèhófà.
3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+
3 Ó máa jókòó bí ẹni tó ń yọ́ fàdákà, tó sì ń fọ̀ ọ́ mọ́,+ ó sì máa fọ àwọn ọmọ Léfì mọ́; á sì yọ́ wọn mọ́* bíi wúrà àti fàdákà, ó sì dájú pé wọ́n á fi ọkàn òdodo mú ọrẹ wá fún Jèhófà.