Jeremáyà 20:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kí nìdí tí ò kúkú fi pa mí nígbà tí mo wà nínú ikùn,Kí inú ìyá mi lè di ibi ìsìnkú miKí oyún wà nínú ikùn rẹ̀ nígbà gbogbo?+ 18 Kí nìdí tí mo fi jáde kúrò nínú ikùnLáti rí ìdààmú àti ẹ̀dùn ọkàn,Láti mú kí àwọn ọjọ́ mi dópin nínú ìtìjú?+
17 Kí nìdí tí ò kúkú fi pa mí nígbà tí mo wà nínú ikùn,Kí inú ìyá mi lè di ibi ìsìnkú miKí oyún wà nínú ikùn rẹ̀ nígbà gbogbo?+ 18 Kí nìdí tí mo fi jáde kúrò nínú ikùnLáti rí ìdààmú àti ẹ̀dùn ọkàn,Láti mú kí àwọn ọjọ́ mi dópin nínú ìtìjú?+