Sáàmù 25:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn tó bẹ̀rù Jèhófà ni ọ̀rẹ́ rẹ̀ tímọ́tímọ́,+Ó sì ń jẹ́ kí wọ́n mọ májẹ̀mú rẹ̀.+ Òwe 3:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Nítorí Jèhófà kórìíra oníbékebèke,+Ṣùgbọ́n àwọn adúróṣinṣin ni ọ̀rẹ́ Rẹ̀ tímọ́tímọ́.+