Sáàmù 72:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Yóò dà bí òjò tó ń rọ̀ sórí koríko tí a gé,Bí ọ̀wààrà òjò tó ń mú kí ilẹ̀ rin.+ Òwe 16:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹni tó bá rí ojú rere ọba, ayé onítọ̀hún á ládùn;Ojú rere rẹ̀ dà bíi ṣíṣú òjò ìgbà ìrúwé.+