-
Jẹ́nẹ́sísì 4:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Tí o bá dá oko, ilẹ̀ ò ní mú èso* rẹ̀ jáde fún ọ. O sì máa di alárìnká àti ìsáǹsá ní ayé.”
-
-
Sáàmù 109:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kí àwọn ọmọ* rẹ̀ máa tọrọ nǹkan kiri,
Kí wọ́n sì máa jáde látinú ilé wọn tó ti di ahoro lọ wá oúnjẹ.
-